Jump to content

Ìpínlẹ̀ Bẹ́núé-Plateau

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Àtúnyẹ̀wò ní 08:22, 17 Oṣù Agẹmọ 2023 l'átọwọ́ Moshood2921 (ọ̀rọ̀ | àfikún)
(ìyàtọ̀) ← Àtúnyẹ̀wò tópẹ́ju | Àtúnyẹ̀wò ìsinsìnyí (ìyàtọ̀) | Àtúnyẹ̀wò tótuntunju → (ìyàtọ̀)
Ìpínlẹ̀ Bẹ́núé-Plateau

Ipinle Benue-Plateau je ipinle tele ni Naijiria. O je dida ni 27 May 1967 lati awon apa Agbegbe Apaariwa o si wa titi di 3 February 1976, nigba ti won pin si ipinle meji - Benue ati Plateau. Ilu Jos lo je oluilu re nigbana.


Awon Gomina Ipinle Benue-Plateau

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]