Jump to content

Lagos Island: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Content deleted Content added
No edit summary
Rescuing 1 sources and tagging 0 as dead.) #IABot (v2.0.9.5
 
(Àwọn àtúnyẹ̀wò inú àrin 4 látọwọ́ àwọn oníṣe kò hàn)
Ìlà 1: Ìlà 1:
[[Fáìlì:1962_Lagos_Island_map_detail_Lagos_Nigeria_txu-oclc-441966035-lagos-1962.jpg|thumb|Àwòrán máàpù Lagos Island]]
[[Fáìlì:1962_Lagos_Island_map_detail_Lagos_Nigeria_txu-oclc-441966035-lagos-1962.jpg|thumb|Àwòrán máàpù Lagos Island]]
Ìsàlẹ̀ Èkó (Lagos Island)<ref name="Encyclopedia Britannica">{{cite web | title=Lagos Island | website=Encyclopedia Britannica | url=https://www.britannica.com/place/Lagos-Island | access-date=2021-04-22}}</ref> jẹ́ àárín gbùngbùn agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ , [[ìpínlẹ Èkó]]. Ó jẹ́ ọ̀kan lára ìjọba ìbílẹ̀ tí wọ́n pín ìpínlẹ̀ Èkó sí. <ref name="Isale Eko – Descendants Union">{{cite web | title=History of Isale Eko – Isale Eko | website=Isale Eko – Descendants Union | url=https://www.omoisaleeko.org/history-of-isale-eko/ | access-date=2021-04-22}}</ref> Nínú ètò ìkànìyàn tó wáyé ní ọdún 2006 nílẹ̀ Nàìjíríà, ìjọba ìbílẹ̀ náà ni ìwọ̀n  èrò tó pọ̀ tó 209,437 ní agbègbè tí kò ju ìwọ̀n ibùsọ̀ 8.7&nbsp;km² <ref name="figshare 2019">{{cite web | title=Population of Lagos State, Nigeria, by Local Government Area in 1996 and 2006. | website=figshare | date=2019-02-13 | url=/articles/dataset/Population_of_Lagos_State_Nigeria_by_Local_Government_Area_in_1996_and_2006_/7714568/1 | access-date=2021-04-22}}</ref>. Ìjọba ìbílẹ̀ Ìsàlẹ̀ Èkó ló kó ìlàjì nínú apá ìwò Oòrùn Lagos Island, nígbà tí apá ìlà Oòrùn Ìsàlẹ̀ Èkó tókù wà ní  abẹ́ àkóso ìjọba ìbílẹ̀ Etí-Ọ̀sà.
Ìsàlẹ̀ Èkó (Lagos Island)<ref name="Encyclopedia Britannica">{{cite web | title=Lagos Island | website=Encyclopedia Britannica | url=https://www.britannica.com/place/Lagos-Island | access-date=2021-04-22}}</ref> jẹ́ àárín gbùngbùn agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ , [[ìpínlẹ Èkó]]. Ó jẹ́ ọ̀kan lára ìjọba ìbílẹ̀ tí wọ́n pín ìpínlẹ̀ Èkó sí. <ref name="Isale Eko – Descendants Union">{{cite web | title=History of Isale Eko – Isale Eko | website=Isale Eko – Descendants Union | url=https://www.omoisaleeko.org/history-of-isale-eko/ | access-date=2021-04-22 | archive-date=2021-04-22 | archive-url=https://web.archive.org/web/20210422135226/https://www.omoisaleeko.org/history-of-isale-eko/ | dead-url=yes }}</ref> Nínú ètò ìkànìyàn tó wáyé ní ọdún 2006 nílẹ̀ Nàìjíríà, ìjọba ìbílẹ̀ náà ni ìwọ̀n  èrò tó pọ̀ tó 209,437 ní agbègbè tí kò ju ìwọ̀n ibùsọ̀ 8.7&nbsp;km² <ref name="figshare 2019">{{cite web | title=Population of Lagos State, Nigeria, by Local Government Area in 1996 and 2006. | website=figshare | date=2019-02-13 | url=/articles/dataset/Population_of_Lagos_State_Nigeria_by_Local_Government_Area_in_1996_and_2006_/7714568/1 | access-date=2021-04-22}}</ref>. Ìjọba ìbílẹ̀ Ìsàlẹ̀ Èkó ló kó ìlàjì nínú apá ìwò Oòrùn Lagos Island, nígbà tí apá ìlà Oòrùn Ìsàlẹ̀ Èkó tókù wà ní  abẹ́ àkóso ìjọba ìbílẹ̀ Etí-Ọ̀sà.


== Àpèjúwe ==
== Àpèjúwe ==
Ìlà 9: Ìlà 9:
Nínún ìtàn, Ìsàlẹ̀ Èkó jẹ́ ilé ìgbé fún àwọn ọmọ ilè Nàj̀íríà tí wọ́n bọ́ lóko ẹ̀rú láti ilẹ̀ Brazil ma ń dé sí láti forí pamọ́ sí. Ọ̀pọ̀ ẹbí ni ó ń gbé ní ibùgbé tí wọ́n ń pè ní Broad Street ní Marina.
Nínún ìtàn, Ìsàlẹ̀ Èkó jẹ́ ilé ìgbé fún àwọn ọmọ ilè Nàj̀íríà tí wọ́n bọ́ lóko ẹ̀rú láti ilẹ̀ Brazil ma ń dé sí láti forí pamọ́ sí. Ọ̀pọ̀ ẹbí ni ó ń gbé ní ibùgbé tí wọ́n ń pè ní Broad Street ní Marina.


Apá àríwá ìsàlẸ̀ Èkó ni ọ̀pọ̀ ilé òun ọjà ti kò gbòòrò wà tí ó sì ma ń sábà kún fọ́fọ́ fún èrò tí ẹsẹ̀ kò sì gbèrò níbẹ̀. Ìjọba ti ń gbìyànjú láti kó àwọn ọ̀nà tún tún síbẹ̀ lóna  àti lè mú àdínkù bá súnkẹrẹ fàkẹre ojú pópó náà kí ọkọ̀ lè ma lọ gaaraga. Ó tún jẹ́ apá ibi tí Ọba Èkó ń gbé (king of Lagos). Bákan náà ni ó jẹ́ ìgbàgbọ́ pé apá agbègbè yìí nìkan ni ọdún Ẹ̀yọ̀ ti lè wáyé ní ìpínlẹ̀ Èkó.
Apá àríwá ìsàlẹ̀ Èkó ni ọ̀pọ̀ ilé òun ọjà ti kò gbòòrò wà tí ó sì ma ń sábà kún fọ́fọ́ fún èrò tí ẹsẹ̀ kò sì gbèrò níbẹ̀. Ìjọba ti ń gbìyànjú láti kó àwọn ọ̀nà tún tún síbẹ̀ lóna  àti lè mú àdínkù bá súnkẹrẹ fàkẹre ojú pópó náà kí ọkọ̀ lè ma lọ gaaraga. Ó tún jẹ́ apá ibi tí Ọba Èkó ń gbé (king of Lagos). Bákan náà ni ó jẹ́ ìgbàgbọ́ pé apá agbègbè yìí nìkan ni ọdún Ẹ̀yọ̀ ti lè wáyé ní ìpínlẹ̀ Èkó.


== Ètò ọrọ̀ ajé ==
== Ètò ọrọ̀ ajé ==
Ọ̀pò ilé  ìfowó-pamọ́ ni ó ní olú ilé-iṣẹ́ wọn ní Ìsàlẹ̀ Èkó, ní èyí tí ilé ìfowó-pamọ́ ima pršuta i sira
Ọ̀pò ilé  ìfowó-pamọ́ ni ó ní olú ilé-iṣẹ́ wọn ní Ìsàlẹ̀ Èkó, ní èyí tí ilé ìfowó-pamọ́ ima pršuta i sira
First Bank of Nigeria jẹ́ ọ̀kan lára wọn tí ó ní olú ilé-iṣé rẹ̀ ní Marina. Ilé ìfowó-pamọ́ mìíràn tí ó tún ní olú ilé-iṣẹ́ níbẹ̀ ni ilé ìfowó-pamọ́ UBA (United Bank for Africa). Àwọn ilé iṣẹ́ ńlá ńlá àti kéréje kéréje mìíràn tí wọ́n wà níbẹ̀ ni : ilé-iṣẹ́ tí ó ń pèsè ohun ìfaná (electrical appliances manufacturers), ilé iṣé tí ó ń bani ralé àti báni kọ́lé (real estate consultancy firms), àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ ló wà nísàlẹ̀ Èkó.<ref name="Ministry of Commerce, Industry and Cooperatives - Lagos State Government">{{cite web | title=About Lagos - Ministry of Commerce, Industry and Cooperatives | website=Ministry of Commerce, Industry and Cooperatives - Lagos State Government | url=https://mcic.lagosstate.gov.ng/about-lagos/ | access-date=2021-04-22}}</ref>
First Bank of Nigeria jẹ́ ọ̀kan lára wọn tí ó ní olú ilé-iṣé rẹ̀ ní Marina. Ilé ìfowó-pamọ́ mìíràn tí ó tún ní olú ilé-iṣẹ́ níbẹ̀ ni ilé ìfowó-pamọ́ UBA (United Bank for Africa). Àwọn ilé iṣẹ́ ńlá ńlá àti kéréje kéréje mìíràn tí wọ́n wà níbẹ̀ ni : ilé-iṣẹ́ tí ó ń pèsè ohun ìfaná (electrical appliances manufacturers), ilé iṣé tí ó ń bani ralé àti báni kọ́lé (real estate consultancy firms), àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ ló wà nísàlẹ̀ Èkó.<ref name="Ministry of Commerce, Industry and Cooperatives - Lagos State Government">{{cite web | title=About Lagos - Ministry of Commerce, Industry and Cooperatives | website=Ministry of Commerce, Industry and Cooperatives - Lagos State Government | url=https://mcic.lagosstate.gov.ng/about-lagos/ | access-date=2021-04-22 | archive-date=2021-04-22 | archive-url=https://web.archive.org/web/20210422140703/https://mcic.lagosstate.gov.ng/about-lagos/ | dead-url=yes }}</ref>
==Àwọn Ibi Pàtàkì Ní Lagos Island ==

<gallery>
Fáìlì:Aerial view of CMS, Lagos Island East, Lagos-Nigeria.jpg|Aerial view of CMS, Lagos Island East, Lagos-Nigeria
Fáìlì:Aerial view of Marina, Lagos Island East, Lagos-Nigeria.jpg|Aerial view of Marina, Lagos Island East, Lagos-Nigeria
Fáìlì:Cathedral Church CMS, Lagos Island East, Lagos-Nigeria.jpg|Cathedral Church CMS, Lagos Island East, Lagos-Nigeria
Fáìlì:Eko Electricity Distribution Company, Marina, Lagos Island.jpg|Eko Electricity Distribution Company, Marina, Lagos Island
Fáìlì:Lagos Cathedral, Marina, Lagos Island.jpg|Lagos Cathedral, Marina, Lagos Island
Fáìlì:Marina Bus Stop, Lagos Island.jpg|Marina Bus Stop, Lagos Island
Fáìlì:Nigerian Ports Authority, Marina, Lagos Island.jpg|Nigerian Ports Authority, Marina, Lagos Island
Fáìlì:Cms, Lagos.jpg|CMS Lagos
Fáìlì:Cms, Motor Park.jpg|CMS Motor Park
Fáìlì:Cms ROAD, Lagos.jpg|CMS road
Fáìlì:Cms Bus Park route to marina, lagos, nigeria 09.jpg|CMS route to Marina, Lagos
Fáìlì:Civic Towers, Ozumba Nbadiwe, Victoria Island, Lagos.jpg|Civic Towers
Fáìlì:Church of the Assumption, Falomo.jpg|Church of the Assumption, Lagos
Fáìlì:1004 building, lekki road, Lagos, Nigeria.jpg|1004 building, lekki road, Lagos
Fáìlì:Marina, Lagos Island .jpg
Fáìlì:Images of Freedom Park 43.jpg|Freedom Park
Fáìlì:Remembrance Arcade, Lagos Island 02.jpg|Remembrance Arcade, Lagos Island
</gallery>
== Àwọn Ìtọ́ka sí ==
== Àwọn Ìtọ́ka sí ==
{{reflist}}
{{reflist}}
Ìlà 20: Ìlà 39:
{{commons category-inline|Lagos Island|'''Lagos Island'''}}
{{commons category-inline|Lagos Island|'''Lagos Island'''}}


* [http://www.lagosislandlg.com/ Lagos Island Local Government]
* [http://www.lagosislandlg.com/ Lagos Island Local Government] {{Webarchive|url=https://web.archive.org/web/20080416182103/http://www.lagosislandlg.com/ |date=2008-04-16 }}
* [https://web.archive.org/web/20100924152945/http://www.nairajunction.com/ lagos employment]
* [https://web.archive.org/web/20100924152945/http://www.nairajunction.com/ lagos employment]
[[Ẹ̀ka:Ìpínlẹ̀ Èkó]]
[[Ẹ̀ka:Ìpínlẹ̀ Èkó]]

Àtúnyẹ̀wò lọ́wọ́lọ́wọ́ ní 19:34, 29 Oṣù Èrèlé 2024

Àwòrán máàpù Lagos Island

Ìsàlẹ̀ Èkó (Lagos Island)[1] jẹ́ àárín gbùngbùn agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ , ìpínlẹ Èkó. Ó jẹ́ ọ̀kan lára ìjọba ìbílẹ̀ tí wọ́n pín ìpínlẹ̀ Èkó sí. [2] Nínú ètò ìkànìyàn tó wáyé ní ọdún 2006 nílẹ̀ Nàìjíríà, ìjọba ìbílẹ̀ náà ni ìwọ̀n  èrò tó pọ̀ tó 209,437 ní agbègbè tí kò ju ìwọ̀n ibùsọ̀ 8.7 km² [3]. Ìjọba ìbílẹ̀ Ìsàlẹ̀ Èkó ló kó ìlàjì nínú apá ìwò Oòrùn Lagos Island, nígbà tí apá ìlà Oòrùn Ìsàlẹ̀ Èkó tókù wà ní  abẹ́ àkóso ìjọba ìbílẹ̀ Etí-Ọ̀sà.

Ìsàlẹ̀ Èkó yìí ló sún mọ́ afonífojì ìyẹn: Lagos Lagoon, níbi tí ó láàbò jùlọ ní erékùṣù ilè-Adúláwọ̀ (Africa), afonífojì yìí ni ó jẹ́ ti àwọn ọmọ Yorùbá kan tí wọ́n ń ṣiṣé ẹja pípa ní abúlé Èkó, agbègbè yìí náà ló di ìlú tun-tun tí tẹrú-tọmọ ti ń wá jíjẹ-mímu wọn lónìí tí ó sì ti tàn tí ó fi dé àwọn agbègbè tó wà ní ìtòsí rẹ̀ káà kiri tí tí dé mainland.

Ìsàlẹ̀ Èkó (Lagos Island) ni ó já pọ̀ mọ́ mainland ní ọ̀nà mẹ́ta pẹ̀lú àwọn afárá méta (1st-3rd mailand bridge).[4] tí ó tóbi tó nà kọjá lórí afonífojì Èkó tí ó fi dé Èbúté Mẹ́ta. Bákan náà ni ó tún já pọ̀ mọ́ agbègbè tí ó sún mọ bíi: Ìkòyí sí  Victoria Island, tó fi dé ibùdókò ọkọ̀ ojú-omi ti Àpápá tí ó dajú kọ apá ìwọ̀ Oòrùn erékùṣù náà, tí ó sì jẹ́ ibùdó ìpatẹ ọjà láàrín ìgboro Èkó, nígbà tí ó jé pé Ìsàlẹ̀ Èkó ní ilé ìṣèjọba, ọjà ìpàtẹ àti àwọn ọfíísì lóríśi ríśi ìjọba ìbílẹ̀ náà wà .Bákan náà ni ilé ìjọ Catholic, ìjọ Àgùdà (Anglican Cathedrals) bẹ́ẹ̀ náà sì ni mọ́sálásí ńlá wà níbẹ̀ pẹ̀lú.

Nínún ìtàn, Ìsàlẹ̀ Èkó jẹ́ ilé ìgbé fún àwọn ọmọ ilè Nàj̀íríà tí wọ́n bọ́ lóko ẹ̀rú láti ilẹ̀ Brazil ma ń dé sí láti forí pamọ́ sí. Ọ̀pọ̀ ẹbí ni ó ń gbé ní ibùgbé tí wọ́n ń pè ní Broad Street ní Marina.

Apá àríwá ìsàlẹ̀ Èkó ni ọ̀pọ̀ ilé òun ọjà ti kò gbòòrò wà tí ó sì ma ń sábà kún fọ́fọ́ fún èrò tí ẹsẹ̀ kò sì gbèrò níbẹ̀. Ìjọba ti ń gbìyànjú láti kó àwọn ọ̀nà tún tún síbẹ̀ lóna  àti lè mú àdínkù bá súnkẹrẹ fàkẹre ojú pópó náà kí ọkọ̀ lè ma lọ gaaraga. Ó tún jẹ́ apá ibi tí Ọba Èkó ń gbé (king of Lagos). Bákan náà ni ó jẹ́ ìgbàgbọ́ pé apá agbègbè yìí nìkan ni ọdún Ẹ̀yọ̀ ti lè wáyé ní ìpínlẹ̀ Èkó.

Ètò ọrọ̀ ajé

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ọ̀pò ilé  ìfowó-pamọ́ ni ó ní olú ilé-iṣẹ́ wọn ní Ìsàlẹ̀ Èkó, ní èyí tí ilé ìfowó-pamọ́ ima pršuta i sira First Bank of Nigeria jẹ́ ọ̀kan lára wọn tí ó ní olú ilé-iṣé rẹ̀ ní Marina. Ilé ìfowó-pamọ́ mìíràn tí ó tún ní olú ilé-iṣẹ́ níbẹ̀ ni ilé ìfowó-pamọ́ UBA (United Bank for Africa). Àwọn ilé iṣẹ́ ńlá ńlá àti kéréje kéréje mìíràn tí wọ́n wà níbẹ̀ ni : ilé-iṣẹ́ tí ó ń pèsè ohun ìfaná (electrical appliances manufacturers), ilé iṣé tí ó ń bani ralé àti báni kọ́lé (real estate consultancy firms), àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ ló wà nísàlẹ̀ Èkó.[5]

Àwọn Ibi Pàtàkì Ní Lagos Island

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn Ìtọ́ka sí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Lagos Island". Encyclopedia Britannica. Retrieved 2021-04-22. 
  2. "History of Isale Eko – Isale Eko". Isale Eko – Descendants Union. Archived from the original on 2021-04-22. Retrieved 2021-04-22. 
  3. [/articles/dataset/Population_of_Lagos_State_Nigeria_by_Local_Government_Area_in_1996_and_2006_/7714568/1 "Population of Lagos State, Nigeria, by Local Government Area in 1996 and 2006."] Check |url= value (help). figshare. 2019-02-13. Retrieved 2021-04-22. 
  4. "Third Mainland Bridge, Lagos". Institution of Civil Engineers (ICE). 2017-05-19. Retrieved 2021-04-22. 
  5. "About Lagos - Ministry of Commerce, Industry and Cooperatives". Ministry of Commerce, Industry and Cooperatives - Lagos State Government. Archived from the original on 2021-04-22. Retrieved 2021-04-22. 

Àwọn ìjápọ̀ ìta

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]