Jump to content

Gbẹ̀du: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Content deleted Content added
lower level category; needs Category:Yoruba musical instruments
#WPWP #WPWPYO
 
Ìlà 1: Ìlà 1:
[[File:Drummers of traditional Gbedu drum in Yoruba land of Nigeria.jpg|thumb|Àwòrán àwọn onílù tó ń lu ìlù gbẹ̀du]]
Pàtàkì ni '''Gbẹ̀du''' jẹ̀ nínú àwọn ìlù ìbílẹ̀ Yorùbá. Ìlù yii kan naa lawọn kan n pen i àgbà. Ìyàńgèdè ni ìlẹ̀ Yorùbá.

Ìlù mẹta la le tọkasi nínú ọwọ ìlù Gbẹ̀du.
Pàtàkì ni '''Gbẹ̀du''' jẹ̀ nínú àwọn ìlù ìbílẹ̀ Yorùbá. Ìlù yii kan naa lawọn kan n pen i àgbà. Ìyàńgèdè ni ìlẹ̀ Yorùbá.<ref name=proverbs>{{cite book
|title=Yoruba proverbs
|author=Oyekan Owomoyela
|publisher=University of Nebraska Press
|year=2005
|ISBN=0-8032-3576-3}}</ref>
Ìlù mẹta la le tọkasi nínú ọwọ ìlù Gbẹ̀du.<ref name=hiphop>{{cite web
|url=http://www.languageinindia.com/feb2009/nigerianhiphop.pdf
|title=Language Alternation Strategies in Nigerian Hip Hop and Rap Texts
|author=Maduabuchi Agbo
|publisher=Language in India
|date=1 February 2009
|page=35
|accessdate=2010-01-30}}</ref>


(a) Aféré:- Ìlù nla ni afẹrẹ. Ó ga tó iwọ̀n ẹsẹ̀ bàtà mẹ́rin ó sì gùn gbọọgì. Géńdé ti ko ba dara rẹ loju ko le gbe nìlẹ. Oùn rẹ̀ máa n rìnlẹ dòdò. Ìkeke ni a fi maa nlù.
(a) Aféré:- Ìlù nla ni afẹrẹ. Ó ga tó iwọ̀n ẹsẹ̀ bàtà mẹ́rin ó sì gùn gbọọgì. Géńdé ti ko ba dara rẹ loju ko le gbe nìlẹ. Oùn rẹ̀ máa n rìnlẹ dòdò. Ìkeke ni a fi maa nlù.
Ìlà 13: Ìlà 27:
== Àwọn ìtọ́kasí ==
== Àwọn ìtọ́kasí ==
{{Reflist}}
{{Reflist}}


{{Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́}}



[[Ẹ̀ka:Àṣà Yorùbá]]
[[Ẹ̀ka:Àṣà Yorùbá]]

Àtúnyẹ̀wò lọ́wọ́lọ́wọ́ ní 15:43, 22 Oṣù Ògún 2023

Àwòrán àwọn onílù tó ń lu ìlù gbẹ̀du

Pàtàkì ni Gbẹ̀du jẹ̀ nínú àwọn ìlù ìbílẹ̀ Yorùbá. Ìlù yii kan naa lawọn kan n pen i àgbà. Ìyàńgèdè ni ìlẹ̀ Yorùbá.[1] Ìlù mẹta la le tọkasi nínú ọwọ ìlù Gbẹ̀du.[2]

(a) Aféré:- Ìlù nla ni afẹrẹ. Ó ga tó iwọ̀n ẹsẹ̀ bàtà mẹ́rin ó sì gùn gbọọgì. Géńdé ti ko ba dara rẹ loju ko le gbe nìlẹ. Oùn rẹ̀ máa n rìnlẹ dòdò. Ìkeke ni a fi maa nlù.

(b) Apéré tabi Opéré: Ìlù yii lo tobi tẹle afẹrẹ labẹ ọmọ ìlù ti a n pe ni Gbẹdu. Igi la fi gbẹẹ, ṣùgbọ́n ko ga, ko si fẹ lẹnu to aféré.

(d) Ọbadan: Ìlù yii lo kere ju nínú ọ̀wọ́ ìlù Gbẹdu. Igi la fi gbẹẹ bi ti awọn yooku. Ko sit obi to apẹẹrẹ rara.

Gbẹdu se patakì pupọ nitori pe o jẹ ìlù ọba. A kii dede n lu u. Ìlù yi wa fun ìyẹ̀sì awọn Ọba ilẹ̀ Yorùbá. Bi ọba ba gbesẹ tabi ijoye nla kan tẹri gbaso wọn n lù Gbẹdu lati fi tufọ.


Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Oyekan Owomoyela (2005). Yoruba proverbs. University of Nebraska Press. ISBN 0-8032-3576-3. 
  2. Maduabuchi Agbo (1 February 2009). "Language Alternation Strategies in Nigerian Hip Hop and Rap Texts" (PDF). Language in India. p. 35. Retrieved 2010-01-30.